TOJU IWA RE ORE MI (Written by the late J.F. ODUNJO in his popular book series ‘ALAWIYE’)
Toju iwa re, ore mi; Ola a ma si lo n'ile eni, Ewa a si ma si l'ara enia, Olowo oni 'nd’olosi b'o d'ola. Okun l'ola; okun n’igbi oro, Gbogbo won l'o nsi lo n’ile eni; Sugbon iwa ni m’ba ni de sare’e. Owo ko je nkan fun ni, Iwa l'ewa omo enia. Bi o l'owo bi o ko ni’wa nko? Tani je f'inu tan e ba s'ohun rere? Tabi ki o je obirin rogbodo; Ti o ba jina si'wa ti eda nfe, Tani je fe o s'ile bi aya? Tabi ki o je onijibiti enia; Bi o tile mo iwe amodaju, Tani je gbe'se aje fun o se? Toju Iwa re, ore mi, Iwa ko si, eko d'egbe; Gbogbo aiye ni 'nfe 'ni t'o je rere. (ENGLISH TRANSLATION not by the Author) Enhance your character, my friend; Prosperity may depart from one’s home, Beauty may retreat from the body, And today’s rich could become poor tomorrow. Prosperity is like ocean surf; and wealth is an ocean wave, They come and go from one’s home as they please; But, only good character follows on...